Ìtàn ni ọ̀pá ọrọ̀ ajé mi – Funke Akindele

Phenomenal
Phenomenal
Funke Akindele
Funke Akindele, producer of A TRIBE CALLED JUDAH

 

Ogbontarigi onifiimu, Funke Akindele, ti se alaye bi itan se je e logun to gege bii alariya.

O ni itan – iyen itan to n di fiimu ti awon oloyinbo n pe ni ‘story – ni opa tabi gbongbo oro aje oun.

Gege bi o ti so, itan lo maa n di fiimu gidi.

Ninu iforowanilenuwo kan pelu iwe iroyin SATURDAY PUNCH, Akindele, eni ti fiimu re ‘Everybody Loves Jenifa’ si n ta warawara ni sinimo, so pe ko si itan ti o dara, bi onifiimu ba se lo itan naa lo se pataki.

O wa ro awon to n bo leyin ki won se akiyesi eleyii, to si so pataki ki won mo kin ni awon oluworan n efe, ki won si fun won ni itan ti o sun o igbesi ayae won.

 

Share this Article